ISE IRANSE AWON ELEDE TABI EYA YORUBA

Mo ki yin ni oruko Jesu Kristi Oluwa!

JESU KRISTI ni Oluwa, fun gbogbo eniyan yala a je Eya Oyinbo tabi ti Yoruba! Ni Ijo Barnaba Mimo yii a n fe lati ki gbogbo eniyan ni orile, eya, ati ede gbogbo (Iwe Ifihan 7:9).

Ti o ba je eya Yoruba, jowo mase jafara lati ri okan lara awon ojise Olorun ti o je okan ninu awon ojise alabasisepo ninu ile ijosin ti Barnaba Mimo yii: Ven Paul S Ogunsakin ti o je okan lara awon ojise Olorun lati Daosisi Akure, ni Ipinle Ondo, ni Orile-ede Naijiria. Oruko iyawo re ni Blessing, ti oruko awon omo re mererin si n je: Shalom, Nancy, Samuel ati Hephzibah.

Ona ti a le gba ba won soro ni yii:

Ven. Paul S Ogunsakin Ogunsakinpaul@gmail.com


Ministry for Yoruba Speakers

Greetings in the name of our Lord Jesus Christ!

Jesus Christ is Lord, for all people, whether we speak English or Yoruba!

And St Barnabas Church seeks to welcome people ‘from every nation, tribe, people and language’ (Revelation 7:9)

If you speak Yoruba, please contact one of the St Barnabas Ministry Team, the Ven. Paul Ogunsakin

The Ven. Paul Ogunsakin is from Akure Diocese, Nigeria and is married to Blessing. They have four children: Shalom, Nancy, Samuel and Hephzibah.

His contact details are below:

The Ven. Paul Ogunsakin – ogunsakinpaul@gmail.com